Codedfilm

  • Category Video
    Nollywood Ghallywood Hollywood Bollywood Goals Highlight Latest Movies BBNaija Mark Angel ApataTv Yorubahood
  • About Us
  • Privacy Policy
  • Copyright Claims
  • Contact Us

Download Oríkì Ìlú Ẹ̀gbá | Eulogy of Ẹ̀gbá Land | AbalayeTV

Loading the player...


Published on 10 April 2018 by Abalaye Television
Views: 6,372
Duration: 03:19

DOWNLOAD HERE

SHARE: Facebook Twitter
Codedwap

Oríkì Ìlú Ẹ̀gbá | Eulogy of Ẹ̀gbá Land | AbalayeTV

Lyrics:Ẹ̀gbá ọmọ Lísàbí,Àgbòǹgbò Àkàlà.Ọmọ erín jogún ọlá,Ọmọ ò-ṣílẹ̀kùn palẹ̀kùndé.Arídìí ògo lójú ogun,Baba tèmi lá a ròyìn ogun Baara f'ágbẹ̀.Ọmọ ẹni dúdú 'ò sí nílé,Pupa tó wà nílé 'ò mọbẹ̀ ẹ́ sè.Kò s'óhun tí wọ́n ń ṣe ní Mẹ́kà,Táwa kì í ṣe l'Ẹ́gbàá ti wa.Wọ́n ń mu'mi sẹ́mí-sẹmì ní Mẹ́kà,Àwa ń mu'mi odò Ògùn l'Ẹ́gbàá.Wọ́n ń gàràfá ní Mẹ́kà,Àwa ń g'òkè Olúmọ l'Ẹ́gbàá ti wa.Ẹ̀gbá ará Aké-màjó,Ọmọ Màjójó l'Ọ́fà,Jòjò l'Ọ́fà kunkundin ń j'ẹni.Ẹ̀yin lọmọ a-jó-gbẹrú, má jò ó gbẹ̀kọ.Nítorí ẹrú ní ń sin ni.Ẹ̀kọ kì í sìnnìyàn.Ọmọ atẹ́ní wíjọ́wíjọ́,Tí irun rẹ̀ ń gbọ̀n ọ́n lẹ̀ tẹẹrẹrẹ.Onírúurú Ẹ̀gbá pọ̀ nílé Aláké,Olúgbọ́njọbí lolórí wọn.Ìjà kan, ìjà kàn tí wọ́n jà lọjà,N ló túlùú Ẹ̀gbá Orílé,N ló sọ Ṣódẹkẹ́ di baba Ogun lábẹ́ Olúmọ.Ẹ̀gbá ọmọ òru là á ṣè'kà,Ẹní ṣe'rú rẹ̀ lọ́sàn-án ńkọ́?Kò ní fara' re lọ.Ẹ̀gbá méjì kì í jara wọn níyàn,B'ọ́kan bá ń wí,Èkejì a sì ní báawà.Onírúurú Ẹ̀gbá pọ̀ nílé Aláké,Ẹ̀gbá Àgùrá, Ẹ̀gbá Òwu,Ẹ̀gbá Òkè-ọnà, Ẹ̀gbá Aláké,Gbogbo wọn ló gba Ìjàyè lálejò lábẹ́ Olúmọ.Èdùmàrè jọ̀wọ́ má jẹ̀ ẹ́ k'ílùú Ẹ̀gbá tú o.Àṣẹ.ORINK'ógun má j'Ẹ̀gbá Aké,K'ógun má j'Ẹ̀gbá Òwu,K'ógun má j'Ọsilẹ̀,K'ógun má j'Àgùrá,K'ógun má ja'Barà,Títí d'Ómidá.Copyright: Abalaye NaijiriaFacebook: www.facebook.com/abalayenigeriaInstagram: www.instagram.com/abalayenigeriaYoutube: AbalayeTVTwitter: www.twitter.com/abalayenigeria



Related Videos
Download Oriki  of the Egbas - one of the Tribes in Nigeria Mp3 and Videos
Oriki of the Egbas - one of the Tribes in Nigeria by: kola falana - 12 year ago
Download ISE YA -OGUN STATE ANTHEM feat ogun all star Mp3 and Videos
ISE YA -OGUN STATE ANTHEM feat ogun all star by: WisdomGateTv - 3 year ago
Download Oríkì Ìlú Ìjẹ̀bú|The Eulogy of Ijebu Town|AbalayeTV Mp3 and Videos
Oríkì Ìlú Ìjẹ̀bú|The Eulogy of Ijebu Town|AbalayeTV by: Abalaye Television - 2 year ago
Download Egbaland anthem by Dr.O Mp3 and Videos
Egbaland anthem by Dr.O by: wings94513 - 4 year ago
Download Ogun State Anthem, Ise ya by Team Definition Mp3 and Videos
Ogun State Anthem, Ise ya by Team Definition by: Team Definition Studios - 1 year ago
Download ORÍKÌ ÌLÚ ÒGBÓMỌ̀ṢỌ́ (Eulogy Of Ògbómọ̀ṣọ́) Mp3 and Videos
ORÍKÌ ÌLÚ ÒGBÓMỌ̀ṢỌ́ (Eulogy Of Ògbómọ̀ṣọ́) by: Janet Ifeoluwa Oyewumi - 2 year ago
Download Oriki Gbagura of Egba Abeokuta (Ashabi Ademefun) Mp3 and Videos
Oriki Gbagura of Egba Abeokuta (Ashabi Ademefun) by: Prodigy and Pens TV - 10 months ago
Download ORÍKÌ OLÚKÒYÍ(Ìkòyí Ẹ̀sọ́ Ọmọ Agbọ̀n Iyún. Ọmọ A Kú Rangbọndan Níjọ́ T'ébi Ń P'ẹyẹ L'óko... Mp3 and Videos
ORÍKÌ OLÚKÒYÍ(Ìkòyí Ẹ̀sọ́ Ọmọ Agbọ̀n Iyún. Ọmọ A Kú Rangbọndan Níjọ́ T'ébi Ń P'ẹyẹ L'óko... by: Oríkì Yorùbá Tv - 6 months ago
Download The Egba Heritage  Lisabi Festival Mp3 and Videos
The Egba Heritage Lisabi Festival by: Egba Heritage - 6 year ago
Download ORIKI EGBA Mp3 and Videos
ORIKI EGBA by: U&I Evergreen TV - 1 year ago
Download ORIKI ILE YORUBA CD 1, ORIKI EGBA,ORIKI EKO,ORIKI IJEBU Mp3 and Videos
ORIKI ILE YORUBA CD 1, ORIKI EGBA,ORIKI EKO,ORIKI IJEBU by: MOSEBOLATAN TV - 2 year ago
Download Oluko Agba nile Balogun Ibikunle Ibadan (Laji Abbas) Mp3 and Videos
Oluko Agba nile Balogun Ibikunle Ibadan (Laji Abbas) by: Itan Yoruba - 2 year ago
Download Oriki ikoyi Esho Mp3 and Videos
Oriki ikoyi Esho by: Apeke Ajobata TV - 7 months ago
Download A Short History of Abeokuta Mp3 and Videos
A Short History of Abeokuta by: HistoryVille - 2 year ago
Download ORIKI ILE YORUBA:ORIKI EJIGBO,IKIRE,EDE,ONIKOYI,OGBOMOSO,IJESHA,IDOFIAN,ETI OSA,EKO, Mp3 and Videos
ORIKI ILE YORUBA:ORIKI EJIGBO,IKIRE,EDE,ONIKOYI,OGBOMOSO,IJESHA,IDOFIAN,ETI OSA,EKO, by: MOSEBOLATAN TV - 2 year ago
Oríkì Ìlú Ẹ̀gbá | Eulogy Of Ẹ̀gbá Land | AbalayeTV
Download Format MP3 :




Download Format Videos :


© Copyright 2021 • Codedfilm • All Rights Reserved